Iyaosha Agbomola Olorun Lo Ni Ewe Ati Egbo

Call Contact the hotel

Iyaosha Agbomola Olorun Lo Ni Ewe Ati Egbo Beyerunka opposite Adeogba hospital Ibadan Oyo state

AGBO OYUN IJU EYIKEYI (FIBROID)Oyun IJU je Arun kan Tino ma ndamu Obinrin nikan ti o si jepe Oni Awon Ohun ti o ma nfa A...
01/09/2026

AGBO OYUN IJU EYIKEYI (FIBROID)
Oyun IJU je Arun kan Tino ma ndamu Obinrin nikan ti o si jepe Oni Awon Ohun ti o ma nfa Arun yi.
Oniruru Aisan iju (Fibroid) yi ni o wa.

Opo Awon Obinrin Ti won ni Ipenija yi ni won ti lo Oniruru Ogun Sugbon sibe sibe kosi Iyato Rara, bi Eniyan base ndagba si ni IJU (fibroid) yi na ma ndagba si.
Ninu Awon iwadi Imo Ijinle, won kofibe ri pato aridaju Ohun ti o le ma fa Aisan yi, sugbon Ninu Awon Ohun ti I saba ma nfa ju ni:

•Arun Ibalopo Olojo Pipe (Long term STI)
•Oyun Sise (Abortion)
•Ifeto somobibi Olojo pipe
(Long term Family planing)
•Apoju Ara sisan
•Riri nkan OSU bi 11/12 yr (Early Period)

Eyi Awon Apere
•Apoju Nkan osu sise (Heavy Meanstrual Bleeding)
•Ogoro Eyin Riro (Lower back Pain)
•Isale Inu rirun (Pelvic Pressure)
•Ito Apoju (Frequent Urination)
•Irora lakoko Ibalopo (Pain during s*x)
•Aikomari Oyun ni (Unable to Conceive)

Ti o ba gbiyanju ohun ti mofe salaye re yi odamiloju pe wamadupe fun olohun oba ni.

Ikan TI a mawa
•Ewe Iyeye Tutu
•Epo igi Amunyan
•Bara
•Kahun Bulala
•Iyo Isebe
•Omidun Agbado

BI AO SESE
Ki a RI daju wipe adi Ewe Iyeye si ona meje,
Ao fi Omi fo Gbogbo Awon Eronja yi nu ki o mo dada, ao ko Gbogbo Awon Eronja yi tele Inu Oru, ao wa ge bara yi Kekeke ao kole Ori re, ao fi Omidun yi se ki o jina dada fun bi Ogbon (45min) iseju Tabi ju belo.

LILO RE
Gass kan ni owuro ati Ale.
Ki a lo Ogun yi fun OSU meta gbako.

Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na.
Lati tunbo RI ekunrere Lori bi a se nlo Ewe Ati Egbo Awon Babanla wa,

Gbogbo wa akonifi Aisan Logba oo 🙏🏿
remedies

Iwo na Bami Comment, like, and share re fun Anfani Awon Elomiran!
‎
‎Mogba ladura pe Gbogbo wa pata so ni FI asan logba lase
Eledumare
‎
‎Fun Ibere Tabi Ohun Miran Tabi ofe ki abo se kia gbe ranse si o
‎Whatssap :- 09133275017
‎08051996013

FOR MORE QUESTIONS ASK 👇👇
This is YEYE ((Many Mother)) AGBOMOLA TRADOMEDICAL FOR ALL Native things, what do you want me to do for you? about your problem mention your problem I will tell you what to do in a Native way
if you want to discuss with me putting your message down or WhatsApp,, call me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about your problem.to no what to do this my WhatsApp number 09133275017 08051996013 or

My Link 👇
https://chat.whatsapp.com/BUV8jWvpNMMJPeUVHrwrZ6
me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about it .to no what to do this my WhatsApp number 09133275017

AYEWO FUN GBOGBO IWO TI OBAFESE IWADI LODOMI AYEWO ( ) DETAILS TO SEND YOUR FULL NAME
SE IWADI AYEWO ORO IGBESI AIYE RE IF YOU ARE READY MESSAGE ME ON WHAT'S APP OR CALL ME

21/08/2026
AGBO FUN KOKO OYAN (BREAST LUMP)Ipenija Koko OYAN (Breast Lump) ti so Opolopo Obinrin di onifunpa giga latara Ironu, Idi...
17/08/2026

AGBO FUN KOKO OYAN (BREAST LUMP)
Ipenija Koko OYAN (Breast Lump) ti so Opolopo Obinrin di onifunpa giga latara Ironu, Idi ni wipe Opo Ipenija Koko OYAN yi lomanpada di Jejere.

Oniruru Awon nkan lo ma nsokun fa Nini Aisan yi,
Ninu iwadi Imo Ijinle, won Jeki o yewa wipe orisi nkan meta lo ma nfa.

•Apoju polatin ju Eje lo (High Prolactin)
•Apoju/Adinku Omonu ju Dede lo
(Hormonal imbalance)
•Kokoro Inu OYAN (Breast Infection)
•Apo Omi Inu OYAN (Breast cyst)

Mofe ki a lo Mo amodaju loni wipe, Gbogbo Ohun ti o batise niunse pelu OYAN Gba Eto Amojuto Gidigidi nitoripe, OYAN ti a nsi yi koni Egun (bone) kankan Ninu sugbon kikida ora (fat) lasan ni, ti Eyi ntumo si wipe o rorun fun Jjr Lati tete SE ijamba fun fun OYAN.
Aisan jjr koni je ipin Emi Ati Iwo 🙏

OHUN TI AOWA
•Epo Aganho
•Egbo Ajoo
•Egbo Ipeta
•Ewe Ogbo Tutu
•Egbo Ayin
•Egbo Dan Cameroon
•Egbo Inabiri
•Epo ira
BI AO SESE
Ao fo Gbogbo Awon Eronja yi nu ki o mo dada, ao wase lagbo papo ki o jina dada fun bi Ogbon iseju (30min).
LILO RE
Mimu ni Gass cup kan ni owuro ati Ale.
Eyikeyi Koko OYAN (Breast Lump) ti o baje, pelu Ase olohun oba, yi yo kuro nibe patapata ni.

Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na ki won o le ba je Anfani yi!

Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo Ase

Ikan tio lese fun mi ni ki
Iwo na Bami Comment, like, and share re fun Anfani Awon Elomiran!
Mogba ladura pe Gbogbo wa pata ni Eledumare ma kole Ayo Fun ooo🙏🙏🙏
Fun Ibere Tabi Ohun Miran Tabi ofe ki abo se kia gbe ranse si o
Whatssap :- 09133275017
08051996013

FOR MORE QUESTIONS ASK 👇👇
This is IYAOSHA ((Many Mother)) AGBOMOLA TRADOMEDICAL FOR ALL Native things, what do you want me to do for you? about your problem mention your problem I will know what to do for you in a Native way
if you want to discuss with me putting your message down or WhatsApp,, me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about it .to no what to do this my WhatsApp number 09133275017 08051996013 or

My Link 👇
https://chat.whatsapp.com/BUV8jWvpNMMJPeUVHrwrZ6
me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about it .to no what to do this my WhatsApp number 09133275017 or 08051996013

02/07/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Olanrewaju Oyekunle, Sunday Ferrary, Muyi Ojo, Fasasi Abdulrauf Rotimi, Olaiwola Nurudeen, Busari Ojo Abdulwasiu Wazlight, Wale Edundokun, Elesaodo Festus Oluwadare, Akomolafe Sanmi Oliver, Ojnap Adex, Afolabi Abiodun John, Ogunbayo Gbenga Alade, Abissola Kanssi, Olanrewaju Wasiu Adewale, Azeez Ajibike, Abimbola Oladimeji, Folohunsho Oluwakhemi, Justus Teluwo, Olayinka Gbadamosi, Çhësčó Pōúvöįr IV, Faleye Adetunji, Matthew Cha, John Kolade Ojugbele, Aminu Opisa Ibrahim Aaziobanyi, Oniyire Samuel, Bamidele Adebayo, Ademola Iliasu, Dauda Opeloyeru, John Ojo Salami, UP Nhykolas, Folayan Adebayo William, Remi Owolabi, Yeye Bajesewa Omiegbetunmise, Adelola Idris, Presh Holak, ID Wise, Kuku Yetunde, Ademola Awotide, Abdul Azeez Sharaf, Ope Confamento, Ibrahim Abdulbakiu, Adewale Isola, Owomide Ogunsipe, Ayuba Olaniyan, Gbenga Ara, Muideen Ajibade, Promise Ayeni, Saheed Amoo, Folashade Muftau, Ajayi Temitayo

ASIRI TI OKUNRIN FIRI OBINRIN AREWA OLOWO OLOLA ENIYAN FENIYI TO DAJU (1)ABO-ADIYE IBILE TO REWA KAN(2) OWO-EYO TI KOLUJ...
27/06/2026

ASIRI TI OKUNRIN FIRI OBINRIN AREWA OLOWO OLOLA ENIYAN FENIYI TO DAJU

(1)ABO-ADIYE IBILE TO REWA KAN
(2) OWO-EYO TI KOLUJU 7.
(3) EFO-EBOLO TOJO.
(4) EFO-ODU TOJO.
(5) ASO-FUNFUN ILAJI OPA.

A Lora abo-adiye ibile tojoju tositun rewa daada kan,,,,, a o tee ILAJI aso funfun yen sile, a o ko owo-eyo 7, silori, a o fi obedu ADIYE naa lorun, a o roo gbogbo eje adiye naa, le owo-eyo naa lori, a o ko gbogbo ifun adiye naa ati OKAN re lelori, a o tun gbe ori adiye naa lelori, a o ko efo ebolo ati efo-odu naa lelori, a o wade ao wa se adura iru obinrin ti abafe si pelu, a o wadi aso naa papo, a o gbe sinu ape Tuntun kan, koni atare ninu ooo, a o wajo papo, akisi iseyiwo t**i yo fi jotan ooo, a o lo ninu ape ti afijo yen ni ooo, a o wa pomo eyikeyi ose tobawu wa, ibase funfun tabi dudu, a o fi omi-agbon ati OYIN gidi popapo daada, a o ko sinu ike funfun kan........Biru okunrin naa, bati fori gbepe latinu iya re wa, tobafi ni anfani lati malo ose yi, Olorun gbo witiwiti ni odo re yomase fun in awon gbajumo olola obinrin koda semi won yo tun maja lelori ni...

Pemi tabi kio message mi ni WhatsApp
Fun Ibere Tabi Ohun Miran Tabi ofe ki abo se kia gbe ranse si o
‎Whatssap :- 09133275017
‎08051996013

Address

Opp/Adeogba Hospital Beyerunka Street Ibadan In
Ibadan
IBADANOYO

Telephone

+2349133275017

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iyaosha Agbomola Olorun Lo Ni Ewe Ati Egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Hotel

Send a message to Iyaosha Agbomola Olorun Lo Ni Ewe Ati Egbo:

Shortcuts

Share